Iṣe Apo 9:15 YCE

15 Ṣugbọn Oluwa wi fun u pe, Mã lọ: nitori ohun elo àyo li on jẹ fun mi, lati gbe orukọ mi lọ si iwaju awọn Keferi, ati awọn ọba, ati awọn ọmọ Israeli:

Ka pipe ipin Iṣe Apo 9

Wo Iṣe Apo 9:15 ni o tọ