Iṣe Apo 9:26 YCE

26 Nigbati Saulu si de Jerusalemu, o pete ati da ara rẹ̀ pọ̀ mọ awọn ọmọ-ẹhin: gbogbo nwọn si bẹ̀ru rẹ̀, nitori nwọn kò gbagbọ́ pe ọmọ-ẹhin kan ni.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 9

Wo Iṣe Apo 9:26 ni o tọ