Iṣe Apo 9:7 YCE

7 Awọn ọkunrin ti nwọn si mba a re àjo duro, kẹ́kẹ pa mọ́ wọn li ẹnu, nwọn gbọ́ ohùn na, ṣugbọn nwọn kò ri ẹnikan.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 9

Wo Iṣe Apo 9:7 ni o tọ