2. Kor 6:3 YCE

3 A kò si ṣe ohun ikọsẹ li ohunkohun, ki iṣẹ-iranṣẹ ki o máṣe di isọrọ buburu si.

Ka pipe ipin 2. Kor 6

Wo 2. Kor 6:3 ni o tọ