2. Kor 6:4 YCE

4 Ṣugbọn li ohun gbogbo awa nfi ara wa han bi awọn iranṣẹ Ọlọrun ninu ọ̀pọlọpọ sũru, ninu ipọnju, ninu aini, ninu wahalà,

Ka pipe ipin 2. Kor 6

Wo 2. Kor 6:4 ni o tọ