Luk 14:17 YCE

17 O si rán ọmọ-odọ rẹ̀ ni wakati àse-alẹ lati sọ fun awọn ti a ti pè wipe, Ẹ wá; nitori ohun gbogbo ṣe tan.

Ka pipe ipin Luk 14

Wo Luk 14:17 ni o tọ