Luk 14:18 YCE

18 Gbogbo wọn so bẹ̀rẹ, li ohùn kan lati ṣe awawi. Ekini wi fun u pe, Mo rà ilẹ kan, emi kò si le ṣe ki ng má lọ iwò o: mo bẹ̀ ọ ṣe gafara fun mi.

Ka pipe ipin Luk 14

Wo Luk 14:18 ni o tọ