27 Ijọ enia pipọ li o ntọ̀ ọ lẹhin, ati awọn obinrin, ti npohùnrere ẹkún, ti nwọn si nṣe idarò rẹ̀.
Ka pipe ipin Luk 23
Wo Luk 23:27 ni o tọ