Luk 23:28 YCE

28 Ṣugbọn Jesu yiju pada si wọn, o si wipe, Ẹnyin ọmọbinrin Jerusalemu, ẹ má sọkun fun mi, ṣugbọn ẹ sọkun fun ara nyin, ati fun awọn ọmọ nyin.

Ka pipe ipin Luk 23

Wo Luk 23:28 ni o tọ