Luk 23:47 YCE

47 Nigbati balogun ọrún ri ohun ti o ṣe, o yìn Ọlọrun logo, wipe, Dajudaju olododo li ọkunrin yi.

Ka pipe ipin Luk 23

Wo Luk 23:47 ni o tọ