Luk 23:48 YCE

48 Gbogbo ijọ enia ti o pejọ si iran yi, nigbati nwọn nwò ohun ti nṣe, nwọn a lù ara wọn li õkan àiya, nwọn a si pada.

Ka pipe ipin Luk 23

Wo Luk 23:48 ni o tọ