Luk 6:32 YCE

32 Njẹ bi ẹnyin ba fẹ awọn ti o fẹ nyin, ọpẹ́ kili ẹnyin ni? awọn ẹlẹṣẹ pẹlu nfẹ́ awọn ti o fẹ wọn.

Ka pipe ipin Luk 6

Wo Luk 6:32 ni o tọ