Luk 9:59 YCE

59 O si wi fun ẹlomiran pe, Mã tọ̀ mi lẹhin. Ṣugbọn o wi fun u pe, Oluwa, jẹ ki emi ki o kọ́ lọ isinku baba mi na.

Ka pipe ipin Luk 9

Wo Luk 9:59 ni o tọ