60 Jesu si wi fun u pe, Je ki awọn okú ki o mã sinkú ara wọn: ṣugbọn iwọ lọ ki o si mã wãsu ijọba Ọlọrun.
Ka pipe ipin Luk 9
Wo Luk 9:60 ni o tọ