1 Kíróníkà 1:19 BMY

19 A bí àwọn ọmọ méjì fún Ébérì:Orúkọ ọ̀kan ni Pélégì, nítorí ní àkókò tirẹ̀ a pín ayé; orúkọ ẹ̀gbọ́n Rẹ̀ ọkùnrin a sì máa jẹ́ Jókítanì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 1

Wo 1 Kíróníkà 1:19 ni o tọ