1 Kíróníkà 1:43 BMY

43 Àwọn wọ̀nyí ni ọba tí ó jẹ ní Édómù, kí ó tó di wí pé àwọn ọba ará Ísírẹ́lì kán jẹ:Bélà ọmọ Béórì, ẹni tí orúkọ ìlú Rẹ̀ a máa jẹ́ Díníhábà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 1

Wo 1 Kíróníkà 1:43 ni o tọ