1 Kíróníkà 1:50 BMY

50 Nígbà tí Báli-hánánì sì kú, Hádádì sì di ọba nípò Rẹ̀. Orúkọ ìlú Rẹ̀ sì ni Páì; àti orúkọ ìyàwó sì ni Méhélábélì ọmọbìnrin Métírédì, ọmọbìnrin Mésíhábù.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 1

Wo 1 Kíróníkà 1:50 ni o tọ