1 Kíróníkà 11:17 BMY

17 Dáfídì sí pòǹgbẹ fún omi ó sì wí pé, Áà, ẹnìkan yóò ha buomi láti inú kànga ní ẹ̀gbẹ́ ẹnu bodè Bẹ́tílẹ́hẹ́mù fún un mu?

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 11

Wo 1 Kíróníkà 11:17 ni o tọ