1 Kíróníkà 11:6 BMY

6 Dáfídì ti wí pé Ẹnikẹ́ni tí ó bá darí àti kọlu àwọn ará Jébúsì ni yóò di olórí balógun, Jóábù ọmọ Sérúíà lọ sókè lákòókọ́, bẹ́ẹ̀ ni ó sì gba olórí.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 11

Wo 1 Kíróníkà 11:6 ni o tọ