1 Kíróníkà 11:8 BMY

8 Ó sì kọ́ àwọn ìlú náà yíkákiri Rẹ̀, láti ọ̀dọ̀ àwọn alátìlẹ́yìn ibi ìtẹ́jú ilẹ̀ si àyíká ògiri. Nígbà tí Jóábù sì pa ìyókù àwọn ìlú náà run.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 11

Wo 1 Kíróníkà 11:8 ni o tọ