1 Kíróníkà 12:15 BMY

15 Àwọn ni ẹni tí ó rékọjá Jọ́dánì ní oṣù àkọ́kọ́ nígbà tí ó kún bo gbogbo bèbè Rẹ̀, wọ́n sì lé gbogbo àwọn tí ó ń gbé nínú àfonífojì, lọ sí ìlà oòrùn àti níhà ìwọ̀ oòrùn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 12

Wo 1 Kíróníkà 12:15 ni o tọ