1 Kíróníkà 12:18 BMY

18 Nígbà náà Ẹ̀mí Mímọ́ wa sórí Ámásáyà ìjòyè àwọn ọgbọ̀n, ó sì wí pé:“Tìrẹ ni àwa ń se, ìwọ Dáfídì!Àwa pẹ̀lú rẹ, ìwọ ọmọ Jésè!Àlàáfíà, àlàáfíà fún o,àti àlàáfíà fún àwọn tí ó ràn ó lọ́wọ́,nítorí Ọlọ́run Rẹ̀ yóò ràn ọ́ lọ́wọ́.”Bẹ́ẹ̀ ni Dáfídì sì gbà wọ́n ó sì mú wọn jẹ olórí ẹgbẹ́ ogun.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 12

Wo 1 Kíróníkà 12:18 ni o tọ