1 Kíróníkà 12:37 BMY

37 Lati ìlà òrùn Jódánì, ọkùnrin Réubénì, Gádì, àti ìdájì ẹ̀yà Mánásè, dìmọ́ra pẹ̀lú gbogbo onírúurú ohun èlò ìjà ọ̀kẹ́ mẹ́fà (120,000).

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 12

Wo 1 Kíróníkà 12:37 ni o tọ