1 Kíróníkà 14:1 BMY

1 Nísinsìn yìí Hírámù àti ọba Tírè rán oníṣẹ́ sí Dáfídì, àti pẹ̀lú igi kédérì pẹ̀lú àwọn ọ̀mọ̀lé àti gbẹ́nàgbẹ́nà láti kọ́ ààfin fún un.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 14

Wo 1 Kíróníkà 14:1 ni o tọ