1 Kíróníkà 15:1 BMY

1 Lẹ́yìn ìgbà tí Dáfídì ti kọ́ ilé fún ara Rẹ̀ ní ìlú Dáfídì. Ó sì fi ààyè sílẹ̀ fún àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run ó sì pàgọ́ fún un.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 15

Wo 1 Kíróníkà 15:1 ni o tọ