1 Kíróníkà 15:25 BMY

25 Bẹ́ẹ̀ ni Dáfídì àti àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì àti àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún lọ láti gbé àpótí ẹ̀rí ti májẹ̀mú Olúwa láti ilé Obedi-Édómù, pẹ̀lú inú dídùn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 15

Wo 1 Kíróníkà 15:25 ni o tọ