3 Dáfídì kó gbogbo àwon ọmọ Ísírélì jọ ní Jérúsálẹ́mù láti gbé àpótí ẹ̀rí Olúwa wá sí ibi tí ó ti pèṣè sílẹ̀ fún un.
Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 15
Wo 1 Kíróníkà 15:3 ni o tọ