1 Kíróníkà 17:13 BMY

13 Èmi yóò jẹ́ bàbá Rẹ̀, Òun yóò sì jẹ́ ọmọ mi. Èmi kì yóò mú ìfẹ́ mi kurò lọ́dọ̀ Rẹ̀ láéláé gẹ́gẹ́ bí mo se mú un kúrò lọ́dọ̀ àwọn aṣáájú Rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 17

Wo 1 Kíróníkà 17:13 ni o tọ