1 Kíróníkà 17:25 BMY

25 “Ìwọ, Ọlọ́run mi, ti fihan ìránṣẹ́ rẹ pé, ìwọ yóò kọ́ ilé fún un. Bẹ́ẹ̀ ni ìransẹ́ rẹ ti ní ìgboyà láti gbàdúrà sí ọ.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 17

Wo 1 Kíróníkà 17:25 ni o tọ