1 Kíróníkà 17:5 BMY

5 Èmi kò tí ì gbé nínú ilé láti ọjọ́ tí mo ti mú Isírẹ́lì jáde wá láti Éjíbítì títí di òní yìí. Èmi ń lọ láti àgọ́ dé àgọ́ àti láti ibùgbé dé ibùgbé.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 17

Wo 1 Kíróníkà 17:5 ni o tọ