1 Kíróníkà 18:1 BMY

1 Ní àkókò kan, Dáfídì kọlu àwọn ará Fílístínì, ó sì sẹ́gun wọn. Ó sì mú Gátì àti àwọn ìlétò agbègbè Rẹ̀ kúrò lábẹ́ ìdarí àwọn ará Fílístínì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 18

Wo 1 Kíróníkà 18:1 ni o tọ