1 Kíróníkà 18:15 BMY

15 Jóábù ọmọ Ṣérúyà jẹ́ olórí ẹgbẹ́ ọmọ ogun; Jéhóṣáfátì ọmọ Áhílúdì jẹ́ akọ̀wé ìrántí;

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 18

Wo 1 Kíróníkà 18:15 ni o tọ