1 Kíróníkà 18:8 BMY

8 Láti Tébà àti Kúnì, ìlú tí ó jẹ́ ti Hádádéṣérì, Dáfídì mú ọ̀pọ̀ tánganran tí Ṣólómónì lò láti fi ṣe òkun tan-gan-ran, àwọn òpó àti orísìí ohun èlò tan-gan-ran.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 18

Wo 1 Kíróníkà 18:8 ni o tọ