12 Jóábù wí pé Tí àwọn ará Ṣíríà bá le jù fún mi, nígbà náà, ìwọ ni kí o gbà mí; Ṣùgbọ́n tí àwọn ará Ámónì bá le jù fún ọ, Nígbà náà èmi yóò gbà ọ́.
Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 19
Wo 1 Kíróníkà 19:12 ni o tọ