1 Kíróníkà 19:15 BMY

15 Nígbà ti àwọn ará Ámónì ri pé àwọn ará Ṣíríà ń sálọ, àwọn náà sálọ kúrò níwájú arákùnrin Rẹ̀ Ábíṣáì. Wọ́n sì wọ inú ìlú ńlá lọ. Bẹ́ẹ̀ ni Jóábù padà lọ sí Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 19

Wo 1 Kíróníkà 19:15 ni o tọ