1 Kíróníkà 2:34 BMY

34 Ṣésánì kò sì ní ọmọkùnrin àwọn ọmọbìnrin nìkan ni ó ní.Ó sì ní ìránṣẹ́ ará Éjíbítì tí orúkọ Rẹ̀ ń jẹ́ Járíhà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 2

Wo 1 Kíróníkà 2:34 ni o tọ