44 Ṣémà ni baba Ráhámú Ráhámù sì jẹ́ baba fún Jóríkéámù. Rékémù sì ni baba Ṣémáì.
45 Àwọn ọmọ Ṣémáì ni Máónì, Máónì sì ni baba Bétí-Ṣúri.
46 Éfà Obìnrin Kélẹ́bù sì ni ìyá Hárà nì, Mósà àti Gásésì, Háránì sì ni baba Gásésì.
47 Àwọn ọmọ Jádáì:Régémù, Jótamù, Gésánì, Pétélì, Éfà àti Ṣáfù.
48 Mákà obìnrin Kélẹ́bù sì ni ìyá Ṣébérì àti Tíránà.
49 Ó sì bí Ṣáfà baba Mákíbénà, Ṣéfà baba Mákíbénà àti baba Gíbéà: ọmọbìnrin Kélẹ́bù sì ni Ákíṣà.
50 Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Kélẹ́bù.Àwọn ọmọ Húrì, àkọ́bí Éfúrátà:Ṣóbálì baba Kiriati-Jéárímù.