1 Kíróníkà 2:7 BMY

7 Àwọn ọmọ Kárímì:Ákárì, ẹni tí ó mú ìyọnu wá sórí Ísírẹ́lì nípa ẹ̀ṣẹ̀ ìfibú lórí mímú ohun ìyàsọ́tọ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 2

Wo 1 Kíróníkà 2:7 ni o tọ