1 Kíróníkà 21:20 BMY

20 Nígbà tí Órínánì sì ń pakà lọ́wọ́, ó sì yípadà ó sì rí áńgẹ́lì; àwọn ọmọ Rẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin tí ó wà pẹ̀lú Rẹ̀ pa ará wọn mọ́.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 21

Wo 1 Kíróníkà 21:20 ni o tọ