1 Kíróníkà 21:29 BMY

29 Àgọ́ Olúwa tí Mósè ti ṣe ní ihà, àti pẹpẹ ẹbọ ọrẹ ṣíṣun wà lórí ibi gíga ní Gíbíónì ní àkókò náà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 21

Wo 1 Kíróníkà 21:29 ni o tọ