1 Kíróníkà 22:12 BMY

12 Kí Olúwa kí ó fún ọ ni ọgbọ́n àti òye nígbà tí ó bá fi ọ́ se aláṣẹ lórí Ísírẹ́lì, Bẹ́ẹ̀ ni kí ìwọ kí ó lè pa òfin Olúwa Ọlọ́run mọ́.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 22

Wo 1 Kíróníkà 22:12 ni o tọ