1 Kíróníkà 23:11 BMY

11 Jáhátì sì ni alákọ́kọ́ Ṣísà sì ni ẹlẹ́kejì, ṣùgbọ́n Jéúsì àti Béríà kò ní àwọn ọmọ púpọ̀; Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì ka ara wọn sí ìdílé kan pẹ̀lú ìfilé lọ́wọ́ kan.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 23

Wo 1 Kíróníkà 23:11 ni o tọ