1 Kíróníkà 23:17 BMY

17 Àwọn ọmọ Élíásérì:Réhábíà sì ni ẹni àkọ́kọ́.Élíásérì kò sì tún ní ọmọ mìíràn, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Réhábíà wọ́n sì pọ̀ níye.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 23

Wo 1 Kíróníkà 23:17 ni o tọ