24 Àwọn ọmọ Húsíélì: Mikà;nínú àwọn ọmọ Míkà: Ṣámírù.
25 Àwọn arákùnrin Míkà: Íṣíà;nínú àwọn ọmọ Íṣíà: Ṣekaríyà.
26 Àwọn ọmọ Mérarì: Málì àti Múṣì.Àwọn ọmọ Jásíà: Bẹ́nò.
27 Àwọn ọmọ Mérárì:Lati Jasíà: Bẹ́nò, Ṣóhámù, Ṣákúrì àti Íbírì.
28 Láti Málì: Élíásérì, ẹni tí kò ni àwọn ọmọ.
29 Láti Kíṣì: Àwọn ọmọ Kíṣì:Jérámélì.
30 Àti àwọn ọmọ Muṣì: Málì, Édérì àti Jérímotì.Èyí ni àwọn ọmọ Léfì, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.