1 Kíróníkà 24:5 BMY

5 Wọ́n sì pín wọn lótìítọ́ nípa yíya ìpín, nítorí àwọn olórí ibi mímọ́ àti àwọn olorí ilé Ọlọ́run wà láàrin àwọn ọmọ méjèèjì Élíásérì àti Ìtamárì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 24

Wo 1 Kíróníkà 24:5 ni o tọ