1 Kíróníkà 25:2 BMY

2 Nínú àwọn ọmọ Ásáfù:Ṣákúrì, Jóṣẹ́fù Nétanáíà àti Ásárélà, àwọn ọmọ Ásáfù ni wọ́n wà lábẹ́ ìbojútó Ásáfù, ẹni tí ó sọtẹ́lẹ̀ lábẹ́ ìbojútó ọba.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 25

Wo 1 Kíróníkà 25:2 ni o tọ