1 Kíróníkà 26:12 BMY

12 Ìpín wọ̀nyí ti àwọn olùtọ́jú ẹnu ọ̀nà nípasẹ̀ olóyè ọkùnrin wọn, ní iṣẹ́ ìsìn fún jíjísẹ́ nínú ilé Olúwa, gẹ́gẹ́ bí ìbátan wọn ti ṣe.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 26

Wo 1 Kíróníkà 26:12 ni o tọ