1 Kíróníkà 26:17 BMY

17 Àwọn ará Léfì mẹ́fà ní ó wà ní ọjọ́ kan ní ìhà ìlà oòrùn, mẹ́rin ní ọjọ́ kan ní ìhà àríwá, mẹ́rin ní ọjọ́ kan ní ìhà gúṣù àti méjì ní ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo ní ilé ìṣúra.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 26

Wo 1 Kíróníkà 26:17 ni o tọ