1 Kíróníkà 26:29 BMY

29 Láti ọ̀dọ̀ àwọn Iṣíhárì: Kénáníà àti àwọn ọmọ Rẹ̀ ni a pín iṣẹ́ ìsìn fún kúrò ní apá ilé Olúwa, gẹ́gẹ́ bí àwọn onísẹ́ àti àwọn adájọ́ lórí Ísirẹ́lì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 26

Wo 1 Kíróníkà 26:29 ni o tọ