31 Jáṣíṣì ará Hágírì wà ní ìdi àwọn agbo-ẹran.Gbogbo wọ̀nyí ni àwọn oníṣẹ́ tí wọ́n wà ní ìdí ẹrù ọba Dáfídì.
32 Jónátanì, arákùnrin Dáfídì jẹ́ olùdámọ̀ràn, ọkùnrin onímọ̀ àti akọ̀wé. Jéhíélì ọmọ Hákímónì bojútó àwọn ọmọ ọba.
33 Áhítófélì jẹ́ olùdámọ̀ràn ọba.Húsáì ará Áríkì jẹ́ ọ̀rẹ́ ọba.
34 Jéhóíádà ọmọ Bẹnáyà àti nípaṣẹ̀ Ábíátárì jọba rọ́pò Áhítófélì.Jóábù jẹ́ olórí ọmọ ogun ọba.